Àwọn ìlànà fún ìdáàbòbò
Àwọn ìlànà fún ìdáàbòbò tó wọ́pọ̀
Gbogbo ètò ni o jẹ́ tí agbègbè
Gbogbo ètò orí pẹpẹ wa lo wàyè ni Nàíjíríà fún ìdí èyí, o jẹ́ ohun tí o lè rorun latí sayẹ̀wò rẹ
Lo Làákàyè
Sá fún àwọn ètò tó rú ẹ lojú tí kò ní ibi tí a tí lè fìdí rẹ múlẹ̀ tàbí tí o mú ìfanimọ́ra aláínìgbẹkẹ̀lẹ́ fún owó tásẹ́rẹ́ tàbí òfẹ́
A ko béèrẹ̀ fún ìròyìn nípa ináwo rẹ
Ma ṣe fi ìròyìn ináwo rẹ , gbogbo ohun tí o jẹ́ mo àbò rẹ tàbí nọ́mbà asíri rẹ èyí tí o lè jẹ́ asílo ránsẹ́
Faràbale sayẹ̀wò àwọn ètò rẹ ki o tó buwo luu
ṣe ayẹ̀wò nnkan wonyi leemeji ibi ètò, eni tó nṣe ètò kinnikinni nípa ontaja ìtàkùn àgbáyé tó sopọ̀ mo. Ki o tó buwo luu. Tí ododo ètò náa ko ba da o lójú jọ̀wọ́ kàn sí egbe alátìlẹyìn oníbàá rà wa níbi
AWURUJU ÀTI ETAN LATÍ SORÀ FÚN
Bìbéèrè fún lílo ọ̀nà atarẹ owó
A kò gbà síṣe atarẹ owó latí ọwọ́ latí ibi kan sí ìbòmíràn bí Western Union tàbí Money Gràm fún tíkẹ́ẹ̀tì yàtọ̀ sí èyí tí àti là kalẹ̀ lorí ìtàkùn àgbáyé wa. Sa fún àwọn ìbéèrè báwonwi ki o sí jọ̀wọ́ fi ẹ̀bẹ̀ bẹ́ẹ̀ tó wa letí lesekese ni rẹports@allevents.ng
Àwọn ilé ìsánwó ayédèrú
Allevents ko fi lianá a n gbà sanwó tàbí aàbò Kankan síta. Jọ̀wọ́ ṣe afisun eni tí o nlọ í-meelì tí o n sọ pé oun yóò ṣe iru iṣẹ́ bayìí. Yerà fún lílo ìlàná sísanwó latí ojú òpó tàbí agbègbè dingi ayafi tí o bá ní idanilójú ọgọ́rùn ún nínú ida ọgọ́rùn ún 100% pé ojúlówó ni wón