Bí a ṣe lè gbé àwọn ètò rẹ làrugẹ

Wọlé sí ojú-òpó rẹ tàbí ki o darapọ̀ latí da ojú-òpó kan sílẹ̀

Tí o ba fi ìgbé ètò rẹ ga wọlé sojú-òpó rẹ tí o ko ba sí ni ojú-òpó darapọ̀ pẹ̀lú í-meelì tàbí orúkọ ìròyìn ìbákẹ́gbẹ́ rẹ

Fìdí í-meelì rẹ múlẹ̀

Fi ìdí ìsopọ̀ tí a fi ránsẹ́ sí àpótí lẹ́tà rẹ múlẹ̀ lẹ́yìn rẹ̀ , lọ sí ojú òpó ìgbàròyìn rẹ wọlé sí ojú òpó aworàn ojú rẹ ki os yan “gbe ètò lárugẹ” níbi tó n safihan ojú-òpó aworàn ojú rẹ

Te ìròyìn nípa àwọn ètò

Ṣe afikun àwọn ètò rẹ ko ìròyìn nípa ètò ki o sí mu larà àwọn ìlànà ìgbé lárugẹ ètò , bàwọn ni o ṣe fe ki ìgbélárugẹ ètò rẹ tí jẹ́ wíwá jade tí o sí n fe ki o jẹ́ gbìgbélárugẹ, lọ sí ibi tó safihan aworàn orí ki o sí te “gbe ètò lárugẹ”

Sanwó latí gbe ètò lárugẹ

Pari ohun tí o béèrẹ̀ fún nípa títe “ìròyìn nípa owó tí o san” tí a ba tí fìdí rẹ̀ múlẹ̀ , a o fi iwe ẹ̀rí pè o sanwó ránsẹ́ sí í-meelì rẹ tàbí nọ́mbà fóònù

Duro de igbàwole latí odo Alábojútó

Ètò rẹ yóò gori afẹ́fẹ́, iná rẹ̀ yóò sí ma a  jó sókè lórí ìtàkùn àgbáyé wa, yóò sí ma hàn ketekete lórí ẹ̀rọ asèwádìí lẹ́yìn tí alábojútó tí gbee yẹ̀wọ̀ tí wón sí gbà a wọlé