Bí a ṣe lè ta àwọn tíkẹ́ẹ̀tì

Wọlé sí ojú òpó ìgbàròyìn rẹ tàbí ki o darapọ̀ sí ibi tí o tí maa dákan sílẹ̀

Tí o ba fe tà tíkẹ́ẹ̀tì , wọlé sórí ojú òpó ìròyìn rẹ , tí okò ba sí ni , dara pọ̀ pẹ̀lú í-meelì tàbí orúkọ ìròyìn ìbákẹ́gbẹ́ rẹ.

Fìdí í-meelì rẹ múlẹ̀

Fi ìdí ìsopọ̀ tí a fi ránsẹ́ sí àpótí lẹ́tà rẹ múlẹ̀ , lẹ́yìn rẹ̀ lọ sí ibi ojú òpó ìgbàròyìn rẹ , wọlé sí ibi aworàn ojú rẹ ki o sí yan “tà àwọn iwe ami rẹ” lórí pátákó tó wa níbi tí ojú rẹ wà.

Te ìròyìn nípa àwọn ètò

Te gbogbo ìròyìn lórí ètò ṣe ìdíyele ki o sí te ìròyìn nípa ojú òpó rẹ níbi tí a tí ri owó gbà lẹ́yìn títà tíkẹ́ẹ̀tì

Duro de igbàwole latí odo alábojútó ètò rẹ yóò gori afẹ́fẹ́ lẹ́yìn tí olutoju tàbí ẹ́ka alábojútó ba tí ye e wo tí wón sí gbà a wọlé