Bí a ṣe lè ra tíkẹ́ẹ̀tì
Ṣe ìwádìí nípa ètò tí o nífẹ̀ẹ́ sí latí ibikibi ni Nàíjíríà
Yan Àwọn Tíkẹ́ẹ̀tì Rẹ
Lẹ́yìn tí a ba tí ri ibi ètò tí o fe lọ , te e yóò sí mu o lọ sí ojú iwe tí iye tí a nta tíkẹ́ẹ̀tì wa
Rà Tíkẹ́ẹ̀tì Rẹ
Yan iye tíkẹ́ẹ̀tì tí o fe , wọlé sorí rẹ pari ohun tí o béèrẹ̀ fún nípa títe ọ̀nà tí o gbà sanwó
Gbà tíkẹ́ẹ̀tì rẹ
Tí a bá tí fìdí ohun tí o bèèrè fún múlẹ̀, oo ri ifìtónilétí aba nínú àpótí í-meelì tàbí fóònù rẹ tí on fi ìdí ohun tí o béèrẹ̀ fún múlẹ̀ àti tíkẹ́ẹ̀tì ìgbàlódé yóò jẹ́ fifi ránsẹ́ sí o èyí tí o le te jadesí afihan rẹ ni ọ̀nà abawo ibi ètò náa
Kaabo sí ọ̀nà ẹ̀rí tó daju latí wo ibi ètò
Fún gbogbo tíkẹ́ẹ̀tì tí o ba rà lórí pẹpẹ wa tí a sí fìdí rẹ múlẹ̀ , àti wọlé rẹ daju gan-an